Saturday, 27 August 2016

Oríkì Ede

Oríkì Ede

Ede màpó arógun,
Iyako agbo
Èyin Ọmọ ají lala ọsọ
Ọmọ ají sọsọ
Ọmọ ají f'ọjọ́ gbogbo dára bí egbin,
Ede ọmọ elepo rédé,
Ọmọ ẹwà a dodo,
Èyin lọmọ arohanran,
Ọmọ aje ń ju,
Èyin lọmọ agbale gbira tó l'ede ilé,
Èyin lọmọ alápò tì'emi tì'emi
Èyin lọmọ arógun má fi t'ìbọn se
Ede ìlú timi Ọlọ́fà iná.

Mo kabiyesi fún ọba Timi agbale, ọba Muniru Adesola Lawal Laminisa 1

Ìlú Ede o ni bàjé o

Àmín láṣẹ èdùmàrè

39 comments:

  1. EDE nimi Tokan Tara, Ede Oni baje o

    ReplyDelete
  2. May Almighty Allah continue blessing Ede land.

    ReplyDelete
  3. Edetinutokanimi ilu ede konibaje laelae

    ReplyDelete
  4. Omo Ede ni mi ni ile sagba
    God bless Ede land God bless Osun state

    ReplyDelete
    Replies
    1. I’m from Ile iya Agba but live in Lagos
      My WhatsApp number
      07030393991

      Delete
  5. Edumare mase je ki ilu Ede ko baje o(Amin).

    ReplyDelete
  6. Ede oni baje o, omo ede nimi ni ile ado legbe ile sagba

    ReplyDelete
  7. God bless Ede land God bless osun state Amen

    ReplyDelete
  8. Am proud of my town ❣️💕

    ReplyDelete
  9. ilu Ede kolibaje omo ede timatima nimi mosije omo ile adaora

    ReplyDelete
  10. Ilu wa ko ni baje

    ReplyDelete
  11. Ede ni mi tokan tokan

    ReplyDelete
  12. Ilu ede o ni baje ooo

    ReplyDelete
  13. Proud of my home town

    ReplyDelete
  14. Ede ni mi tokan Tara ilu Ede oni baje ooooo

    ReplyDelete
  15. Ede ni mi tan kan tan kan

    ReplyDelete
  16. Ede ni mi tokam tara

    ReplyDelete
  17. I’m proud of my home town Ede lati ile Agboja 💕

    ReplyDelete
  18. Kinni nkan ewo ti omo ede kogbodo je

    ReplyDelete
  19. Ilu ede onibaje o

    ReplyDelete
  20. Ede Oni baje Ede ni mi tokantokan

    ReplyDelete
  21. Ede nimi tokan tata

    ReplyDelete
  22. Lawal Qosim Ademola29 June 2023 at 21:35

    Èdè nimi tokan tokan

    ReplyDelete
  23. Ede nimi tokan tokan

    ReplyDelete
  24. God blessed Ede land

    ReplyDelete
  25. Am proud of my town cos by now we are at the top and we will never come down never

    ReplyDelete
  26. God bless Ede land

    ReplyDelete
  27. God bless ede land and Nigerian

    ReplyDelete
  28. EDE ni mi tokan tokan

    ReplyDelete
  29. God bless ede land

    ReplyDelete
  30. God bless EDE

    ReplyDelete
  31. O ma dara si oo

    ReplyDelete
  32. Kim ni ipa tire, Abi ti idile re?

    ReplyDelete